Kọrinti Kinni 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mò ń sọ èyí, nǹkankan wà tí n kò yìn yín fún, nítorí nígbà tí ẹ bá péjọ, ìpéjọpọ̀ yín ń ṣe ibi ju rere lọ.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:9-20