Kọrinti Kinni 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa jiyàn lórí ọ̀rọ̀ yìí, kí ẹ mọ̀ pé ní tiwa, a kò ní oríṣìí àṣà mìíràn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ninu àwọn ìjọ Ọlọrun.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:9-20