Kọrinti Kinni 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ìbáà jẹ́ pé ẹ̀ ń jẹ ni, tabi pé ẹ̀ ń mu ni, ohunkohun tí ẹ bá ń ṣe, ẹ máa ṣe é fún ògo Ọlọrun.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:26-33