Kọrinti Kinni 10:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá jẹ oúnjẹ pẹlu ọpẹ́ sí Ọlọrun, ẹ̀tọ́ wo ni ẹnìkan níláti bá mi wí fún ohun tí mo ti dúpẹ́ fún?

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:20-32