Kọrinti Kinni 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí burẹdi kan ni ó wà, ninu ara kan yìí ni gbogbo wa sì wà, nítorí ninu burẹdi kan ni gbogbo wa ti ń jẹ.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:15-19