Kọrinti Kinni 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ife ibukun tí à ń dúpẹ́ fún, ṣebí àjọpín ninu ẹ̀jẹ̀ Kristi ni. Burẹdi tí a bù, ṣebí àjọpín ninu ara Kristi ni.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:10-20