Kọrinti Kinni 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ẹ ní ọpọlọpọ ẹ̀bùn ninu Kristi: ẹ ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ sísọ, ẹ sì tún ní ẹ̀bùn ìmọ̀.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:1-9