Kọrinti Kinni 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun mi nígbà gbogbo nítorí yín, nítorí oore-ọ̀fẹ́ tí Ọlọrun fun yín ninu Kristi Jesu.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:1-6