Kọrinti Kinni 1:28 BIBELI MIMỌ (BM)

bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun yan àwọn ẹni tí kò níláárí ati àwọn ẹni tí kò já mọ́ nǹkankan rárá, àwọn tí ẹnikẹ́ni kò kà sí, láti rẹ àwọn tí ayé ń gbé gẹ̀gẹ̀ sílẹ̀.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:18-31