Kọrinti Kinni 1:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun ti yan àwọn nǹkan tí ayé kà sí agọ̀ láti fi dójú ti àwọn ọlọ́gbọ́n, ó yan àwọn nǹkan tí kò lágbára ti ayé, láti fi dójú ti àwọn alágbára;

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:26-29