Kọrinti Kinni 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn lójú àwọn tí Ọlọrun pè, ìbáà ṣe Juu tabi Giriki, Kristi yìí ni agbára Ọlọrun, òun ni ọgbọ́n Ọlọrun.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:22-31