Kọrinti Kinni 1:23 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn ní tiwa, àwa ń waasu Kristi tí wọ́n kàn mọ́ agbelebu. Ohun ìkọsẹ̀ ni iwaasu wa yìí jẹ́ lójú àwọn Juu, ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ sì ni lójú àwọn orílẹ̀-èdè yòókù;

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:19-29