Kọrinti Kinni 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ipò wo wá ni àwọn ọlọ́gbọ́n wà? Àwọn amòfin ńkọ́? Àwọn tí wọ́n mọ iyàn jà ní ayé yìí ńkọ́? Ṣebí Ọlọrun ti sọ ọgbọ́n ayé yìí di agọ̀!

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:11-24