Kọrinti Kinni 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,“Ọlọrun wí pé, ‘Èmi óo pa ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n run,n óo pa ìmọ̀ àwọn amòye tì sápá kan.’ ”

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:16-29