Kọrinti Kinni 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé Kristi kò fi iṣẹ́ ṣíṣe ìrìbọmi rán mi, iṣẹ́ iwaasu ìyìn rere ni ó fi rán mi, kì í sìí ṣe nípa ọ̀rọ̀ ọgbọ́n, kí agbelebu Kristi má baà di òfo.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:10-27