Kọrinti Kinni 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún ranti! Mo ṣe ìrìbọmi fún ìdílé Stefana. N kò tún ranti ẹlòmíràn tí mo ṣe ìrìbọmi fún mọ́.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:9-17