Kọrinti Keji 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rán àwọn arakunrin sí yín, kí ọwọ́ tí a fi ń sọ̀yà nípa yín lórí ọ̀rọ̀ yìí má baà jẹ́ lásán. Gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ, kí ẹ ti múra sílẹ̀.

Kọrinti Keji 9

Kọrinti Keji 9:1-5