Kọrinti Keji 8:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ti Titu, ẹlẹgbẹ́ mi ati alábàáṣiṣẹ́ mi ni ninu ohun tí ó kàn yín. Ní ti àwọn arakunrin wa, òjíṣẹ́ àwọn ìjọ ni wọ́n, Ògo Kristi sì ni wọ́n.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:12-24