Kọrinti Keji 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

A tún rán arakunrin wa tí a ti dánwò ní oríṣìíríṣìí ọ̀nà ní ti ìtara rẹ̀ pé kí ó bá wọn wá. Nisinsinyii ó túbọ̀ ní ìtara pupọ nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé yín pupọ.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:11-24