Kọrinti Keji 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà wa kò yé àwọn eniyan, sibẹ gbogbo eniyan ni ó mọ̀ wá. A dàbí ẹni tí ń kú lọ, sibẹ a tún wà láàyè. A ti ní ìrírí ìtọ́ni pẹlu ìjìyà, sibẹ ìjìyà yìí kò pa wá.

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:8-12