Kọrinti Keji 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

A ní ìrírí ìbànújẹ́ nígbà gbogbo, sibẹ à ń yọ̀. A jẹ́ aláìní, sibẹ a ti sọ ọpọlọpọ di ọlọ́rọ̀. A dàbí àwọn tí kò ní nǹkankan, sibẹ a ní ohun gbogbo.

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:7-13