Kọrinti Keji 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà tí wọ́n nà wá ati nígbà tí a wà lẹ́wọ̀n, ní àkókò ìrúkèrúdò ati ní àkókò tí iṣẹ́ wọ̀ wá lọ́rùn, tí à ń pa ebi mọ́nú.

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:1-15