Kọrinti Keji 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ninu gbogbo nǹkan, à ń fi ara wa sípò àyẹ́sí gẹ́gẹ́ bí iranṣẹ Ọlọrun. A ti fara da ọpọlọpọ nǹkan ní àkókò inúnibíni, ninu ìdààmú, ati ninu ìṣòro;

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:1-7