Kọrinti Keji 6:17-18 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Nítorí náà ẹ jáde kúrò láàrin wọn,ẹ ya ara yín sọ́tọ̀, ni Oluwa wí.Ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́,kí n lè gbà yín.

18. N óo jẹ́ baba fun yín,ẹ̀yin náà óo sì jẹ́ ọmọ fún mi,lọkunrin ati lobinrin yín.Èmi Oluwa Olodumare ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Kọrinti Keji 6