Kọrinti Keji 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ẹ jáde kúrò láàrin wọn,ẹ ya ara yín sọ́tọ̀, ni Oluwa wí.Ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́,kí n lè gbà yín.

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:14-18