Kọrinti Keji 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, kì báà jẹ́ pé a wà ninu ilé ti ibí, tabi kí á bọ́ sinu ilé ti ọ̀hún, àníyàn wa ni pé kí á sá jẹ́ ẹni ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Oluwa.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:1-14