Kọrinti Keji 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti sọ, a ní ìgboyà. Inú wa ìbá sì dùn kí á kúrò ninu àgọ́ ti ara yìí, kí á bọ́ sinu ilé lọ́dọ̀ Oluwa.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:6-10