Kọrinti Keji 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ìfẹ́ Kristi ni ó ń darí wa, nígbà tí a ti mọ̀ pé ẹnìkan ti kú fún gbogbo eniyan, a mọ̀ pé ikú gbogbo eniyan ni ó gbà kú.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:11-19