Kọrinti Keji 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ ọkunrin onigbagbọ kan ní ọdún mẹrinla sẹ́yìn. Bí ó wà ninu ara ni o, bí ó rí ìran ni o, èmi kò mọ̀–Ọlọrun ni ó mọ̀. A gbé ọkunrin yìí lọ sí ọ̀run kẹta.

Kọrinti Keji 12

Kọrinti Keji 12:1-10