Kọrinti Keji 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó yẹ kí n fọ́nnu. Rere kan kò ti ibẹ̀ wá, sibẹ n óo sọ ti ìran ati ìfarahàn Oluwa.

Kọrinti Keji 12

Kọrinti Keji 12:1-11