Kọrinti Keji 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù ń bà mí pé kí ẹ̀tàn má wọ inú ọkàn yín, tí ẹ óo fi yà kúrò ninu òtítọ́ ati ọkàn kan tí ẹ fi wà ninu Kristi, bí ejò ti fi àrékérekè rẹ̀ tan Efa jẹ.

Kọrinti Keji 11

Kọrinti Keji 11:1-8