Kọrinti Keji 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń jowú nítorí yín, bí Ọlọrun tií jowú. Nítorí èmi ni mo ṣe ètò láti fà yín fún Kristi bí ẹni fa wundia tí ó pé fún ọkọ rẹ̀.

Kọrinti Keji 11

Kọrinti Keji 11:1-10