Kọrinti Keji 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ati gbogbo ìdínà tí ó bá gbórí sókè tí ó lòdì sí ìmọ̀ Ọlọrun. A mú gbogbo èrò ọkàn ní ìgbèkùn kí ó lè gbọ́ràn sí Kristi lẹ́nu.

Kọrinti Keji 10

Kọrinti Keji 10:1-6