Kọrinti Keji 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí àwọn ohun-ìjà wa kì í ṣe ti ayé, agbára Ọlọrun ni, tí a lè fi wó ìlú olódi. À ń bi gbogbo iyàn jíjà lórí èké ṣubú,

Kọrinti Keji 10

Kọrinti Keji 10:1-11