Kọrinti Keji 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kì í ṣe pé a kọjá àyè wa nígbà tí a dé ọ̀dọ̀ yín, àwa ni a sì kọ́kọ́ mú ìyìn rere Kristi dé ọ̀dọ̀ yín.

Kọrinti Keji 10

Kọrinti Keji 10:10-15