Kọrinti Keji 10:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní tiwa, a kò ní lérí ju bí ó ti yẹ lọ. Òṣùnwọ̀n wa kò tayọ ààlà tí Ọlọrun ti pa sílẹ̀ fún wa, tí a fi mú ìyìn rere dé ọ̀dọ̀ yín.

Kọrinti Keji 10

Kọrinti Keji 10:5-17