Joṣua 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n hú wọn jáde ninu àgọ́ rẹ̀, wọ́n kó wọn wá siwaju Joṣua ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì tẹ́ wọn kalẹ̀ níwájú OLUWA.

Joṣua 7

Joṣua 7:14-26