Joṣua 7:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá ranṣẹ, wọ́n sáré lọ wo inú àgọ́ rẹ̀, wọ́n bá àwọn nǹkan náà ní ibi tí ó bò wọ́n mọ́, ó fi fadaka tẹ́lẹ̀.

Joṣua 7

Joṣua 7:13-26