Joṣua 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan náà kọ ilà abẹ́ tán, olukuluku wà ní ààyè rẹ̀ ninu àgọ́ títí egbò wọn fi jinná.

Joṣua 5

Joṣua 5:1-11