Joṣua 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ọmọ wọn tí OLUWA gbé dìde dípò wọn ni Joṣua kọ ilà abẹ́ fún, nítorí pé ẹnikẹ́ni kò kọ wọ́n ní ilà ní ojú ọ̀nà.

Joṣua 5

Joṣua 5:6-14