Joṣua 21:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìlú tí wọ́n fún àwọn ọmọ Lefi ninu ilẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli jẹ́ mejidinlaadọta pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn.

Joṣua 21

Joṣua 21:33-45