Joṣua 21:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìlú mejila ni wọ́n fún àwọn ìdílé yòókù ninu ẹ̀yà Lefi tí à ń pè ní Merari gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.

Joṣua 21

Joṣua 21:37-45