Joṣua 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìpín ti ẹ̀yà Bẹnjamini gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn wà ní ààrin ilẹ̀ ẹ̀yà Juda ati ti ẹ̀yà Josẹfu.

Joṣua 18

Joṣua 18:10-12