Joṣua 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yà Lefi nìkan ni Mose kò pín ilẹ̀ fún, ẹbọ tí àwọn ọmọ Israẹli bá rú sí OLUWA ni ìpín tiwọn. Bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Joṣua 13

Joṣua 13:5-15