Joṣua 13:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ àwọn ọmọ Israẹli kò lé àwọn ará Geṣuri ati àwọn ará Maakati jáde; wọ́n ń gbé ààrin àwọn ọmọ Israẹli títí di òní olónìí.

Joṣua 13

Joṣua 13:10-16