Joṣua 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua ṣe bí OLUWA ti pàṣẹ pé kí ó ṣe sí wọn: ó dá àwọn ẹṣin wọn lẹ́sẹ̀, ó sì sun àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn níná.

Joṣua 11

Joṣua 11:5-17