Joṣua 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá yipada, ó gba ìlú Hasori, ó sì fi idà pa ọba wọn, nítorí pé Hasori ni olú-ìlú ìjọba ilẹ̀ náà tẹ́lẹ̀ rí.

Joṣua 11

Joṣua 11:5-14