Joṣua 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli kò sun èyíkéyìí ninu àwọn ìlú tí wọ́n kọ́ sórí òkítì níná, àfi Hasori nìkan ni Joṣua dáná sun.

Joṣua 11

Joṣua 11:3-19