Joṣua 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua gba gbogbo ìlú àwọn ọba náà, ó kó àwọn ọba wọn, ó fi idà pa wọ́n, gẹ́gẹ́ bí Mose iranṣẹ OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Joṣua 11

Joṣua 11:3-14