Joṣua 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jabini ọba Hasori, gbọ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó ranṣẹ sí Jobabu, ọba Madoni, ati sí ọba Ṣimironi, ati sí ọba Akiṣafu,

Joṣua 11

Joṣua 11:1-7